CCC Hymn 243

1: Mimọ Mimọ Mimọ

YorubaHoly Spirit
Hymn 243Yoruba
1: Mimọ Mimọ Mimọ Si Oluwa Ọlọrun Awọn ọmọ ogun 2: Ọba Oga Ogo Gbogbo aye kun fun ogoo rẹ Ajuba rẹ lọọjọ oni lorukọ Mimọ ọ rẹ