CCC Hymn 242

1: Adaba Ọrun

YorubaHoly Spirit
Hymn 242Yoruba
1: Adaba Ọrun Wọn ti sọkalẹ Adaba Ọrun Wọn ti sọkalẹ Wa ba wa gbe Wa pẹlu wa Adaba Ọrun Wọn si ti de, 2: Ẹni Mimọ Orun Mimọ mimọ ni Ẹni Mimọ Orun Mimọ mimọ ni Wa ba wa gbe Wa pẹlu wa Ẹni Mimọ Ọrun Wa bukun wa, 3: Jesu mimọ wa Mimọ Ọba Iye Jesu mimọ wa Mimọ Ọba Iye Wa ba wa gbe Wa pọlu wa Jesu mimọ wa De wa lade 4: Ẹyin ogun ọrun Mimọ mimọ ni Ẹyin ogun ọrun Mimọ mimọ ni Wa ba wa gbe Wa pẹlu wa Ẹyin ogun ọrun Sẹgun fun wa. Amin