Hymn 243·YorubaCopy Hymn 2431: Mimọ Mimọ Mimọ Si Oluwa Ọlọrun Awọn ọmọ ogun 2: Ọba Oga Ogo Gbogbo aye kun fun ogoo rẹ Ajuba rẹ lọọjọ oni lorukọ Mimọ ọ rẹ