CCC Hymn 970

ONA igbala odo Jesu Oluwa

YorubaSong and Praise
Hymn 970Yoruba
ONA igbala odo Jesu Oluwa Olugbala lo wa, Aiye ati ododo, T’Oluwa dun, Oruko Jesu Oluwa O to gba ni, Ara gbagbo, Ara gbaa gbo, Lati gba ade ogo. Amin