CCC Hymn 965

1. BABA segun fun wa,

YorubaSong and Praise
Hymn 965Yoruba
1. BABA segun fun wa, Omo segun fun wa, Jesu Kristi Oluwa Oba anu, Segun fun wa k’oro wa d’ayo. 2. Baba gb’ase wa se, Omo gba’se wa se, Jesu Mimo, Oluwa Oba anu, Gba’se wa se, K'oro wa d’ayo. 3. Baba wa wo wa san, Omo wa wo wa san, Jesu Mimo, Oluwa Oba anu, Wa wo wa san, K'oro wa d'ayo. 4. Baba gb'adura wa, Omo, gb'adura wa, Jesu Mimo, Oluwa Oba anu, Gb'adura wa k'oro wa dayo. 5. Baba d’abo bo wa Omo d'abo bo wa Jesu Mimo, Oluwa D’abo bo wa, k oro wa d'ayo. 6. Baba fun wa l’agbara Omo fun wa l'agbara Jesu Mimo, Oluwa Oba anu Fun wa l’agbara K’oro wa d’ayo. 7. Baba bukun fun wa Omo bukun fun wa Jesu Mimo, Oluwa Oba anu Wa bukun wa, k'oro wa d'ayo. Amen