CCC Hymn 949

OGO, Ogo, iyin, iyin

YorubaSong and Praise
Hymn 949Yoruba
OGO, Ogo, iyin, iyin Iyin f’Oluwa, Oba Orun A mu iyin at’ope wa Gbadura wa o Oba Rere. Amin