CCC Hymn 947

1. MO f'aiye mi fun Jesu,

YorubaSong and Praise
Hymn 947Yoruba
1. MO f'aiye mi fun Jesu, Mo f’aiye mi fun Jesu, Mo f’aiye mi fun Jesu, K’aiye mi ba le dara. 2. Baba alawo ko le gba ni la, Oni segun ko le gba ni la, Adahunse kole gba ni la, Afi Jesu nikan. Amin