Hymn 926·YorubaCopy Hymn 926KO Oba ko sokale, Ko wa gbawa loni K’o Oba Mimo k’o sokale Kowa gbawa la loni Ninu ijo mimo yii lonii Ko wa d’emi gigun si fun wa. Amin