CCC Hymn 908

BI gbogbo aiye d’ite mo wa,

YorubaPromise
Hymn 908Yoruba
BI gbogbo aiye d’ite mo wa, Nwon gbodo teriba f’Oluwa, Enyin omo Ijo Mimo, Edi de k’enyin Oluwa, Halleluya ni orin wa, Halleluya wa ninu ise wa, Bi aiye fe bi aiye ko, Won teriba fun Kristi Won teriba fun Kristi. Amin