CCC Hymn 888

Oluwa Oluwa Olugbala

YorubaSeeking Favour
Hymn 888Yoruba
Oluwa Oluwa Olugbala Mo mu ẹdun ọkam wa fun ọ Emi ko ni owo lati fifun ọ Emi ko ni owo lati fifun ọ Mo mu ẹdun ọkam wa fun ọ Ann ke pe ọ o dahun Sara ke pe ọ o dahun Mo mu ẹdun ọkam wa fun ọ. Amin