CCC Hymn 889

1: Nigba ye se Ọlọrun da mi

YorubaSeeking Favour
Hymn 889Yoruba
1: Nigba ye se Ọlọrun da mi La woran ara rẹ O fẹ’mi si ọ si fasẹ Aye yi fun mi 2: Ifẹ yipo ngba mo fẹ ro Pa-sẹ re mo Kosi koro kosi damu Ọkan sinmi 3: Sugbọn esu ojowu ni Ri ẹwa ọrun Lara mi bi Ọmọ Ọlọrun O komi lẹsẹ 4: Mo subu sinu ibinu Baba Mo dẹni nrago Adun ifẹ wa di ikoro Nipa ibinu rẹ 5: Oluranwọ kosi fun mi Kosa la ba ro Lati yọ mi kuro Ninu o fin iparun 6: Ninu irako ikoro Ni Jesu Mimọ Boju wolẹ lat’ọrun wa O kẹ dun fun mi 7: O’tara sasa wa sa’ye Fun rapada mi O bọ ogo ọrun silẹ Ojiya fun mi 8: Ninu irako ikoro Ni Jesu Mimọ Boju wolẹ lat’ọrun wa Ojiya fun mi 9: Agun loko atutọ si A si gba loju Oke roro lori igi Fun mi kinle ye 10: Ifẹ yipọ Jesu Kristi Mo d’aji gbse Kini mo le ṣse laye mi Kin fi m’ore han 11: Mo fi gbogbo aye fun ọ Gba mowa laye Mofẹ kin ku kin si jinde Sinu iye Rẹ. Amin