CCC Hymn 878

1. Halleluyah, ayo wa mbo

YorubaSeeking Favour
Hymn 878Yoruba
1. Halleluyah, ayo wa mbo Awon angeli t’orun mbo Lati mu ibukun wa fun wa K’ayo wa le ba wa dopin. Chorus: Awa ti nwoju oluwa K’a mase je ki are mu wa Gbogbo wa la o ri bukun gba Lagbara baba wa orun. 2. Halleluyah ayo wa de Awon angeli t’orun de ‘won ti mu bukun wa fun wa Kayo wa le ba wa dopin. Chorus: Awa ti nwoju oluwa... Amin