CCC Hymn 877

1. JESU l’ojo anu yi,

YorubaSeeking Favour
Hymn 877Yoruba
1. JESU l’ojo anu yi, Awon agan nwo oju Re, To r’ekun kikoro won, Ma je k’agan ‘fe re. 2. Wakati na de kankan, A wole lor ’ekun wa, Ma jeka pofo laiye, F’omo rere fun wa. Amin