CCC Hymn 856

Ka lọ si Bethlehem

YorubaBirth of Christ
Hymn 856Yoruba
Ka lọ si Bethlehem Ta ti bi Jesu Ka lọ si Bethlehem Ta ti bi Jesu, Awọn irawọ ọrun Wọn bu si ayọ Awọn irawọ ọrun Wọn bu si ayọ, Si Olugbala to wa Lati ko ẹṣẹ aye lọ. (2ce) Amin