Hymn 853Yoruba
KALO wo o ni Bethlehem,
Lati bi Jesu,
Kalo we o ni Bethlehem,
Lati bi Jesu,
E bu sayo, e bu sayo,
Pelu awon Angeli Mimo t’Orun,
Ebu sayo, e bu sayo,
Pelu awon Angeli Mimo t’Orun,
Awon ‘rawo Orun won ‘bu si ayo,
Awon ‘rawo Orun won ‘bu si ayo,
F’Olugbala to wa lati
ko ese aiye lo,
F’Olugbala to wa lati
ko ese aiye lo,
Enyin Angeli Mimo t’orun,
E bu sayo, pelu awon
rawo Mimo t’Orun.
Amin
