CCC Hymn 802

1. BA WA tunse Baba,

YorubaProtection and Travel
Hymn 802Yoruba
1. BA WA tunse Baba, Ba wa tunse, Omo. Chorus: Jesu Mimo Oluwa Oba Anu, Ba wa tunse ki ti wa dayo. 2. Wa wo wa san, Baba wa wo wa san Omo wa wo wa san. Chorus: Jesu Mimo Oluwa Oba Anu... 3. Wa gbe wa ga, Baba, wa gbe wa ga, Omo wa gbe wa ga. Chorus: Jesu Mimo Oluwa Oba Anu... 4. Segun fun wa, Baba segun fun wa, Omo segun fun wa. Chorus: Jesu Mimo Oluwa Oba Anu... 5. Dabo bo wa, Baba dabo bo wa, Omo dabo bo wa. Chorus: Jesu Mimo Oluwa Oba Anu... 6. Pese funwa, Baba pese fun wa, Omo pese funwa. Chorus: Jesu Mimo Oluwa Oba Anu... Amen