CCC Hymn 79

Esin, Oluwa ninu Ijo Mimo yi,

YorubaService
Hymn 79Yoruba
Esin, Oluwa ninu Ijo Mimo yi, Ijo kan, Mimo ti Baba Orun ni, K’Oluwa o wa gba awa elese la, K’O si kawa fikun awon ayanfe Re. Amin