CCC Hymn 797

1: Ba wa tun ṣe Oluwa,

YorubaPrayer
Hymn 797Yoruba
1: Ba wa tun ṣe Oluwa, Ba wa tun ṣe Oluwa, Orọ wa ọsan wa alẹ wa o. Ba wa tun ṣe Oluwa. 2: Jẹ ko yẹ wa Oluwa, Jẹ ko yẹ wa Oluwa, Orọ wa ọsan wa alẹ wa o. Ba wa tun ṣe Oluwa. Amin