CCC Hymn 763

1. OLUWA Olugbala jo gba wa la,

YorubaHoly Communion
Hymn 763Yoruba
1. OLUWA Olugbala jo gba wa la, Awa eni mimo l’orun Mimo, Awon Angeli si nyo pelu wa, Jo da wa lohun. 2. Bo tile pe Olugbala na yio wa, L’ti gba ‘wa elese la, Dandan l’Oluwa nso fun wa, Jo da wa lohun. 3. Wa dandan lati da wa l’ohun, Awon to tan fitila Mimo Re Awon fitila Mimo Re meje, Jo da wa lohun. Amin