CCC Hymn 74

1. Eyo, e yo, e yo

YorubaService
Hymn 74Yoruba
1. Eyo, e yo, e yo Enyin omo ‘Jo Mimo Ayo ni Baba wa, E yo, e yo, e yo. 2. E mura sesin yi, Enyin omo ‘Jo Mimo Esin yi yio bori, E yo, e yo, e yo. 3. Igba ‘kehin na de, Enyin omo ‘Jo Mimo, E di Oluwa mu, E yo, e yo, e yo. 4. Aiye yi le sin wa, Enyin omo ‘Jo Mimo, E mura sesin yi, Ke ba le ri Baba E yo, e yo, e yo. 5. Ajinde ni Baba, Baba wa orun wa, Ologo meta ni, E yo, e yo, e yo. 6. Ninu ayo lawa wa, Awa Maleka Orun Ayo ninu Kristi, Ayo, ayo, ayo. 7. Awon agutan Jesu, E si ‘se Baba nyin, ayo yin yio si po, ninu Kristi Jesu. 8. Ijo Mimo Orun, T’aiye ‘yio gba aiye la, E si ‘se Oluwa, K’aguntan le po si 9. E f’ogo f’Oluwa, Enyin omo ‘Jo Mimo, Ogo ni fun Baba, Ogo, Ogo, Ogo. Amin