CCC Hymn 741

IFE tani awa fi wa laiye?

YorubaDivine Love
Hymn 741Yoruba
IFE tani awa fi wa laiye? Ife Jesu ni awa fi wa laiye, Ife tani awa fi wa laiye Ife Jesu ni awa fi wa laiye, Tani ka f’ope fun? Jesu ni ka f’Ope fun, Tani ka f’ope fun? Jesu ni ka f’ope fun Ka foribale fun, Ka f’okan bale fun Ka foribale fun, Ka f’okan bale fun, Ife Jesu ni awa fi wa laiye. Amin