CCC Hymn 703

Nigba t’Oluwa so ‘Jo Mimo ka le,

YorubaRevelation
Hymn 703Yoruba
Nigba t’Oluwa so ‘Jo Mimo ka le, Pelu awon ogun orun Mimo, Nigba t’Oluwa so ‘Jo Mimo ka le, Pelu awon ogun orun Mimo, Oluwa je k’a mo wipe, Ijo Mimo yi, tire ni, K’awa le f’orin ayo, Yin awon ogun Orun Mimo. Chorus: E yo, e yo, e yo, E yin Baba pelu ife Mimo Halleluya, E yo, e yo, e yo, E yin Baba pelu ife Mimo. Amin