CCC Hymn 693

1. WAKATl na de,

YorubaHeavenly Call
Hymn 693Yoruba
1. WAKATl na de, Enyin omo ‘Jo Mimo, E mura sile de Baba yin, 2. Ipe kehin dun, T'awon Maleka fun ipe, E duro de ore ofe Re. 3. Eyin Oluwa, Oko ikehin de, E yo ninu Kristi ‘Jo Mimo. Amin