Hymn 672Yoruba
1. Gbo bi ipe na ti n dun lorun
Jesu duro ni bode orun
Lati ko awon ayanfe Re
Lo si ori ite Baba
2. Awon Angeli kun fayo
Nwon nfun fere pelu ayo,
Baba ka mi mo awon eyi,
Ki nle ri Jesu lojo na.
3. Ore-ofe Re Baba la ntoro
Agbara ati imisi Orun
Ko wa ba wag be e lojo oni,
K’Alleluya le je orin wa.
Amin
