Hymn 608·YorubaCopy Hymn 6081. Toju ise re, Ijo Mimo, Toju ise re, Ijo Mimo, L’ori oke ohun petele, Oju mi nwo ‘se yin loke Orun. 2. Iteriba, Ijo Mimo, Iteriba, Ijo Mimo, E sododo, enyin Ijo Mimo, Oju mi nwo ‘wa yin l’oke Orun. Amin