CCC Hymn 602

1. Ayo Oluwa pe titi

YorubaGod's Work
Hymn 602Yoruba
1. Ayo Oluwa pe titi Ayo titi aiye. Chorus: Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Baba wa sure fun wa. 2. Enyin ogun Orun, e wa Ke wa gbase yi se. Chorus: Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Baba wa sure fun wa. 3. Enyin aiye, e was a yo, E wa sinu oye, Chorus: Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Baba wa sure fun wa. 4. Aiye, e wa sinu ‘mole Irawo meta lo le, Chorus: Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Baba wa sure fun wa. 5. E wa Oga Ogo, Baba, Waiye pelu ikanu, Chorus: Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Baba wa sure fun wa. 6. Enyin omo Ijo Mimo, E tewo ke gba ‘bukun, Chorus: Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Ninu Ise Re lawa nyo, Baba wa sure fun wa. Amin