CCC Hymn 584

1: Imọlẹ yo wa, yo wa

YorubaThe Coming of Jesus
Hymn 584Yoruba
1: Imọlẹ yo wa, yo wa Agbara yo wa yo wa Gbogbo rẹ yo si jẹ Ogo Ijọ Mimọ Chorus: Irawọ didan yo tan Irawọ Ikẹhin Eyi ti, yo wẹ aiye mọ Ẹ gba Jesu wa gbọ. 2: Nigba ti akoko na Yo de ba wa ninu rẹ Gbogbo wa yo si yin Ọba Olugbala. Chorus: Irawọ didan yo tan Irawọ Ikẹhin Eyi ti, yo wẹ aiye mọ Ẹ gba Jesu wa gbọ. 3: Gbogbo wa yo si fo lọ Pade Oluwa Ọba Arẹ ki yo sii fun wa Ni ọjọ ikẹhin, Chorus: Irawọ didan yo tan Irawọ Ikẹhin Eyi ti, yo wẹ aiye mọ Ẹ gba Jesu wa gbọ. Amin