Hymn 583Yoruba
1: Jesu wa nbọ
Jesu wa nbọ
Jesu wa nbọ wa
Lati pin ere
Lati pin ere
Fun onikaluku
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ
Ẹnyin ọmọ Celestial
Ẹ kun fun ayọ
Ẹ ho iho ayọ
Nitori Jesu nbọ wa
2: O mu ayọ nbọ
O mu ayọ nbọ
Fun awọn ọmọ Rẹ
Fun awọn ọmọ Rẹ
To ti gbọ tirẹ
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ
Ẹnyin ọmọ Celestial
Ẹ kun fun ayọ
Ẹ ho iho ayọ
Nitori Jesu nbọ wa
3: Ẹnyin ọmọ Ogun (2ce)
Ẹ damure inyin
Lati ja Ogun
Latin ja Ogun
Pẹlu satani
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ etc
4: Ẹ mase saare (2ce)
Ninu Ogun yi
Ki satani
Ki satani
Mase bori nyin
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ etc
5: Emi ni Alfa (2ce)
Ati Omega
To wa pẹlu nyin
To wa pẹlu nyin
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ etc
6: Ẹ di amure (2ce)
Kọju mọ eṣu
Ẹnyin yio bori
Ẹnyin yio bori
Ki Ade Iye
File jẹ tiwa
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ etc
7: Jesu nyin bọ (2ce)
Ninu Ijọba Rẹ
Ki Ade Iye
Ki Ade Iye
File jẹ tiwa
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ etc
8: Yio mu wa lọ (2ce)
Ninu Ijọba Rẹ
Ki Ade Iye
Ki Ade Iye
File jẹ tiwa
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ etc
9: Halleluya (2ce)
Ni yio jẹ tiwa
Nigbati a gba
Nigbati a gba
Iye ainipẹkun
Chorus: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ
Ẹnyin ọmọ Celestial
Ẹ kun fun ayọ
Ẹ ho iho ayọ
Nitori Jesu nbọ wa.
Amin
