CCC Hymn 580

1. Nigbati fere Oluwa yio dun,

YorubaThe Coming of Jesus
Hymn 580Yoruba
1. Nigbati fere Oluwa yio dun, Ti ise ki o si mo, A o pe ohun alaye ‘gun merin wa, Lati fi ise won han, Ni’waju Olugbala wa, Nigbati fere yio dun, emi o wa nibe, Chorus: Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati fere yio dun Emi o wa nibe. 2. Awa yio ma korin, Lati owuro ti ti dale, Awa yio ma f’Ogo fun Olorun, Olugbala yio ma pe gbogbo wa ni Omo rere, Chorus: Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati fere yio dun Emi o wa nibe. 3. Awa olurapada yio ‘fo, T’aro ki yio mu wa, Lati pade ‘Lugbala Jesu Kristi, Awa yio wa ni abe ‘ye Olorun titi aiye, Alleluia ni orin wa yio ma je, Chorus: Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati, fere yio dun, lohun, Nigbati fere yio dun Emi o wa nibe. Amin