CCC Hymn 536

1. Eda to mola ko si,

YorubaFaith
Hymn 536Yoruba
1. Eda to mola ko si, Eda to mola ko si, Eda to mola ko si, Asan laiye nse. 2. Imo asan ni t’aiye, Imo asan ni t’aiye, Imo asan ni t’aiye, Asan laiye nse. 3. Sagbeke le Oluwa, Sagbeke le Oluwa, Sagbeke le Oluwa, Sagbeke re le. Amin