CCC Hymn 52

1. Oluwa Olugbala,

YorubaService
Hymn 52Yoruba
1. Oluwa Olugbala, Oluwa Olugbala, Jehovah Olugbala, Yio si gbo ti wa. 2. Oluwa Oba Iye, Oluwa Oba Iye, Kristi Oba Imole O mbe lodo wa. 3. E kepe Oba Ogo, E kepe Oba Mimo, E kepe Oba Iye, Yio si gbo oro wa. 4. Oba ti ko gbagbe, Oba ti ko gbagbe, Oba ti ko gbagbe, Ijo Mimo Re. 5. Awon Angeli mbe, Awon Angeli mbe, Awon Angeli mbe, Ninu ayo nla. 6. Iyin fun Oba Mimo, Iyin fun Oba nla Ogo ni fun Oba nla, Fun ise Re ni. 7. E ke Halleluya, E ke Halleluya, E ke Halleluya, Pelu ‘fe Mimo. Amin