CCC Hymn 529

Gbeke re le Oluwa ninu Ijo Mimo yi,

YorubaFaith
Hymn 529Yoruba
Gbeke re le Oluwa ninu Ijo Mimo yi, Gbeke re le Oluwa ninu Ijo Mimo yi, Ijo Mimo nla kan ni, Nibiti Kristi wa a, Okan mi nfe nigbagbogbo, Lati ba Oluwa gbe, Okan mi nfe nigbagbogbo, Lati ba Oluwa gbe. Amin