Hymn 523·YorubaCopy Hymn 523BO ti wu Baba lo nse ise Re, Awamaridi ni lawon ise Re, Ari pase Re lori Okun, Orun, Osupa pelu awon ‘rawo ri, Won wa riri. Amin