Hymn 478Yoruba
Bi gbogbo aye ditẹ mọ wa,
Wọn gbọdọ tẹriba fun Oluwa
Ẹyin ọmọ Ijọ Mimọ
E dide ki ẹ yin Oluwa
Halleluya ni orin wa
Halleluya wa ninu ise wa
Bi aye fẹ bi aye kọ
Wọn tẹriba fun Oluwa
Halleluya ni orin wa
Halleluya wa ninu ise wa
Bi aye fẹ bi aye kọ
Wọn tẹriba fun Kristi.
Amin
