CCC Hymn 470

OBA Edumare, Oba toto,

YorubaVictory
Hymn 470Yoruba
OBA Edumare, Oba toto, Oba Edumare, Oba toto, Atobi julo ninu awon orun Oba aseyi owu, Oba awimayehun asoro matase, Oba agbenu omo enia f’ohun, Oba ogo, Agbara igbega, Ire l’oni, Agbara idalare ire lo ni, Agbara itota mole ire loni Gbe wa ga loni o Oba ogo, Gbe wa ga loni o, Oba ogo. Amin