Hymn 469·YorubaCopy Hymn 4691. K'OBA Mimo ko sokale, Ko wa gba wa loni, K’Oba Mimo ko sokale, Ko wa gba wa loni. 2. Ninu ijo Mimoyi loni, Kowa d’emi gigun si fun wa, Ninu ljo Mimo yi loni, Kowa d’emi gigun si. Amin