Hymn 384·YorubaCopy Hymn 384EJE ka f’ope fun Baba, Orun, Osupa wa ninu imole, Enia ko ni agbara, L’ori Ijo Mimo yi, Oba Orun lo fi ranse, Awon angeli nyo, won nyo, Won nyo ninu Kristi, Awon angeli nyo, won nyo, Won nyo ninu Kristi. Amin