CCC Hymn 282

1. BABA wa, Omo sokale,

YorubaGood News
Hymn 282Yoruba
1. BABA wa, Omo sokale, Lori ‘te Mimo Re, Lati mu ibukun ati Ogo f'omo Re 2. Baba orun mbe ninu ayo, Pelu awon Angeli, Jesu Kristi, Baba wa nyo pelu won. 3. E ke Hossanah si Oba wa, Oluwa Olubukun, T’ombe ninu Tempili re Mimo, O Si nyo. 4. Baba wa Orun sokale sire, Pelu awon Ogun Orun Awon Si busi ayo fun Ijo Mimo yi. 5. E ke Halleluya , s'Oba wa Awa Elese yi. Nitoripe Emi Oluwa mbe lotito. 6. Ka fope fun Olorun wa, Fun ise Re gbogbo Iyanu ni ise Re, lori awa eda. 7. 'Jo Celestial, Ijo Mimo T'Emi oluwa bukun, Nitori ese aiye po, l'ase mu yi wa. 8. Kawa elese yiwa pada, T’ori idajo wole, lo ri awon eni ibi, l'emi o se yi. Amin