Hymn 242Yoruba
1: Adaba Ọrun
Wọn ti sọkalẹ
Adaba Ọrun
Wọn ti sọkalẹ
Wa ba wa gbe
Wa pẹlu wa
Adaba Ọrun
Wọn si ti de,
2: Ẹni Mimọ Orun
Mimọ mimọ ni
Ẹni Mimọ Orun
Mimọ mimọ ni
Wa ba wa gbe
Wa pẹlu wa
Ẹni Mimọ Ọrun
Wa bukun wa,
3: Jesu mimọ wa
Mimọ Ọba Iye
Jesu mimọ wa
Mimọ Ọba Iye
Wa ba wa gbe
Wa pọlu wa
Jesu mimọ wa
De wa lade
4: Ẹyin ogun ọrun
Mimọ mimọ ni
Ẹyin ogun ọrun
Mimọ mimọ ni
Wa ba wa gbe
Wa pẹlu wa
Ẹyin ogun ọrun
Sẹgun fun wa.
Amin
