CCC Hymn 230

1. Emi Mimo

YorubaHoly Spirit
Hymn 230Yoruba
1. Emi Mimo sokale wa O, KO wa fun wa Iagbara. 2. Jesu Oluwa o, sokalewa O, KO wa fun wa lagbara. 3. Adaba Mimo, sokale wa o, Ko wa fun wa lagbara. 4. Maleka Mimo sokale wa o, Ko wa fun wa lagbara. 5. Ogun orun Mimo, sokale wa o, Ko wa fun wa lagbara. 6. Emi Mimo, Sokale wa o Ko wa fun wa lagbara. Amin