Hymn 185Yoruba
E YINOluwa Halleluya,
Eyin Oluwa Halleluya, Eleda Orun,
lyanu ni ise Re gbogbo Halleluya,
Oba awon Oba Halleluya,
Oluse ohun gbogbo Halleluya,
E wa, k’ajo sin ninu ljoMimo
Halleluya, E wa k'asin pelu iteriba,
K’asin pelu ibowo,
Osi tij’Oba
Halleluya,
Lori Satani Halleluya,
EKe Halleluya,enyin araiye.
Amin
