CCC Hymn 183

1. IYE! Iye! Iye! ni ti wa,

YorubaEaster
Hymn 183Yoruba
1. IYE! Iye! Iye! ni ti wa, Oluwa Olufe, O fe ife iye si wa. 2. Lat'orun Mimo, nwon nko orin ayo, Hossanah, Ogo la o ma ko, Ni 'nu Ijo Mimo. Amin