Hymn 152Yoruba
Ranti mi Oluwa,
Oluwa jo ranti mi,
Gba t’aiye ko mi sile,
Oluwa lo nranti mi,
Gba t’aiye de kun fun mi,
Oluwa lo nranti mi,
Gbati mo sa laini
Oluwa lo nranti mi,
Ranti mi Oluwa,
Oluwa jo ranti mi,
Ranti mi Oluwa,
Oluwa jo ranti mi.
Amin
