CCC Hymn 11

JESU awa de pel’ aimo wa,

YorubaForgiveness
Hymn 11Yoruba
JESU awa de pel’ aimo wa, Dariji wa o, ko si busi fun wa Alaini ni wa, Oba Imole Dariji wa o, ko si se wa l’ogo. Amin