CCC Hymn 816

Masai si wa lọ si Kanaan

YorubaProtection and Travel
Hymn 816Yoruba
Masai si wa lọ si Kanaan Masai si wa lọ si Kanaan Alejo l’awa nse Awa ninun irin ajo Masai si wa lọ si Kanaan O pe wa, pe wa, pe wa O pe wa s’ijọ mimọ O pe wa, pe wa, pe wa O pe wa si Celestial. Amin