Hymn 775Yoruba
mm mm mmrm d
mm fm r dt d r
dd rtd
sssdm
mm rm d
m f r dtdrtd
sssdm
mm rm d
m f r dtdrtd
1: Mimọ mimọ mimọ ni imọlẹ
Imọlẹ Kristi to sọkalẹ sori ayanfẹ
Gbogbo awọn to gba Imọlẹ yi gbọ
yio riye iye ayeraiye
Gbogbo awọn to gba Imọlẹ yi gbọ
yio riye iye ainipẹkun
2: Ẹwa ẹwa ẹwa sin Jesu
Ninu ifẹ kan to fi pe wa
Sinu Ijọ mimọ
Ẹgbọrọ Rọ gbọ
Kẹ ṣe ifẹ Rẹ
Ka le ri iye ayeraye
