CCC Hymn 775

mm mm mmrm d

YorubaHoly Re-Union
Hymn 775Yoruba
mm mm mmrm d mm fm r dt d r dd rtd sssdm mm rm d m f r dtdrtd sssdm mm rm d m f r dtdrtd 1: Mimọ mimọ mimọ ni imọlẹ Imọlẹ Kristi to sọkalẹ sori ayanfẹ Gbogbo awọn to gba Imọlẹ yi gbọ yio riye iye ayeraiye Gbogbo awọn to gba Imọlẹ yi gbọ yio riye iye ainipẹkun 2: Ẹwa ẹwa ẹwa sin Jesu Ninu ifẹ kan to fi pe wa Sinu Ijọ mimọ Ẹgbọrọ Rọ gbọ Kẹ ṣe ifẹ Rẹ Ka le ri iye ayeraye