Hymn 696Yoruba
1: Ẹ wo ile wura
T’a pese fun ijọ mimọ
Ile alayọ ile ologo
Ibi isimi aiyeraiye
Ch: Ẹ mura a, ẹ mura
Ẹ mura a, fun ‘le ologo
Ẹ mura a, ẹ mura
Ẹ mura a, fun ‘le ologo.
2: Ipe na ndun kikan
Awọn Maleka nyọ
Lati pade awon aynfẹ rẹ
To sin pẹlu ifẹ mimọ
Ch: Ẹ mura a, ẹ mura
Ẹ mura a, fun ‘le ologo
Ẹ mura a, ẹ mura
Ẹ mura a, fun ‘le ologo.
3: Ẹyin ọmọ ijọ mimọ
Ẹ wa ninu isọna
Ọpọ yio jogun aiye yi
Yio si padamu ‘jọba ọrun
Ch: Ẹ mura a, ẹ mura
Ẹ mura a, fun ‘le ologo
Ẹ mura a, ẹ mura
Ẹ mura a, fun ‘le ologo.
4: Ọpọ ni a bukun fun
Ninu ijọ mimọ
Nwọn yio jpgun aiye yi
Nwọn yio jogun ijọba ọrun
Ch: Ẹ mura a, ẹ mura
Ẹ mura a, fun ‘le ologo
Ẹ mura a, ẹ mura
Ẹ mura a, fun ‘le ologo.
