CCC Hymn 696

1: Ẹ wo ile wura

YorubaHeavenly Call
Hymn 696Yoruba
1: Ẹ wo ile wura T’a pese fun ijọ mimọ Ile alayọ ile ologo Ibi isimi aiyeraiye Ch: Ẹ mura a, ẹ mura Ẹ mura a, fun ‘le ologo Ẹ mura a, ẹ mura Ẹ mura a, fun ‘le ologo. 2: Ipe na ndun kikan Awọn Maleka nyọ Lati pade awon aynfẹ rẹ To sin pẹlu ifẹ mimọ Ch: Ẹ mura a, ẹ mura Ẹ mura a, fun ‘le ologo Ẹ mura a, ẹ mura Ẹ mura a, fun ‘le ologo. 3: Ẹyin ọmọ ijọ mimọ Ẹ wa ninu isọna Ọpọ yio jogun aiye yi Yio si padamu ‘jọba ọrun Ch: Ẹ mura a, ẹ mura Ẹ mura a, fun ‘le ologo Ẹ mura a, ẹ mura Ẹ mura a, fun ‘le ologo. 4: Ọpọ ni a bukun fun Ninu ijọ mimọ Nwọn yio jpgun aiye yi Nwọn yio jogun ijọba ọrun Ch: Ẹ mura a, ẹ mura Ẹ mura a, fun ‘le ologo Ẹ mura a, ẹ mura Ẹ mura a, fun ‘le ologo.