Hymn 449·YorubaCopy Hymn 4491: Baba sẹgun fun wa Ọmọ sẹgun fun wa Jesu Mimọ Oluwa Ọba anu Sẹgun fun wa k’ọrọ wa dayọ 2: Baba gbaṣẹ wa ṣe Ọmo gbaṣẹ wa ṣe Jesu Mimọ Oluwa Ọba anu Gbasẹ wa ṣe, k’ọrọ wa dayọ. Amin